Christianity and the World - Junior Yoruba
Transcript
Christianity and the World - Junior Yoruba
ln k Bibeli k 13 Fn d SN IGBAGB ATI AY I Johannu 2:15-17; Romu 12:1, 2; 2 Krinti 6:14-18; Deuteronomi 7:1-6; Isaiah 3:16-24; Efesu 5:11-13; Isaiah 28:15-18; Kolosse 3:14-17 Aksori: “ me fran aiye, tabi ohun ti mb ninu aiye” (1 Johannu 2:15). r Iaaj Jesu f ki awn mlyin R j oninudidun. Nigba ti pari r ikyin R plu awn Apsteli ki to di p a kan An m agbelebu, s p, “Nkan wnyi ni mo ti s fun nyin, ki ay mi ki o le w ninu nyin, ati ki ay nyin ki o le kn” (Johannu 15:11). n fn wn ni nnkan ti yoo fi ay kn kn wn. Igbala kuro ninu , ati awn iriri ti m ti o jinl, maa n m ay w sinu ay wa: ugbn eniyan ni w, a nilo ifararora awn lgb wa ati idaraya awn eniyan lati fun wa ni ay nigba ti a si n gb lori il ay. Onigbagb gbd fi iy si ir awn r ti n yn. gbd yn lati e ohun ti o t, ki i e ki a f l si igbadun . Onipsalmu k p, “gb gbogbo awn ti o bru r li emi” (Orin Dafidi 119:63). lrun s wi p, “ k m pe ibar aiye it lrun ni? Nitorina nikni ti o ba f lati j r aiye di t lrun” (Jakbu 4:4). Bayii, a w rii bi ti e pataki t fn wa lati yan awn r wa laaarin awn ti fran lrun. gbs 1: a) Ta ni Onigbagb? Johannu 1:12; Romu 8:14; 2 Krinti 5:17; 1 Johannu 3:9. b) Ki ni ay? Gbogbo ilana, gbogbo eniyan, gbogbo mi, ti o tako tabi lodi si Ofin lrun ati Ihinrere Jesu ni ay. 1 Johannu 2:16. Ki ni e ti Onigbagb fi ni lati yra fn ay? 2 Krinti 6:14-18; Jakbu 4:4; 1 Johannu 2:15-17. gbs 2: Ir awn r wo ni Onigbagb gbd n? Orin Dafidi 119:63; Malaki 3:16; Orin Dafidi 1:1, 2; Owe 1:10; Efesu 5:11. gbs 3: Ki ni awn af ay ti gbay ti m lrun k gbd ni ipin ninu r? Ile ij, ile ifi aworan onina hn, kika awn iwe ti n fi aim ati ifkuf ay hn, wiwo aworan ti n fi ihoho hn, lil si awn ibi ti bur lori r itakun agbay, ie ariya, sg mmu, t mimu, ifigagbga lori er idaraya, ibalop kunrin ati obinrin lna ti lodi si ofin d, ati b b l. Galatia 5:19-21; 2 Timoteu 3:3-5; Owe 21:17; 23:5, 31-35; 1 Krinti 6:12. gbs 4: a) Ki ni Bibeli s nipa if ow? 1 Timoteu 6:10. b) Ta ni yoo r lrun? Matteu 5:8; Heberu 12:14. Ikadi r p eniyan ninu ay ni k ka Bibeli. Wn n wo kunrin tabi obinrin, mdekunrin tabi mdebinrin ti n s p Onigbagb ni oun. Nj iw j si Ihinrere ti Jesu Kristi? Nj iwa mim ati didara r le fa ni ti n w mra? Tabi ni e ni n da ara r p m ay, ti o si n e bi wn ti n e ki o m b a d yat? “Ki m si da ara nyin p m aiye yi: ugbn ki parada lati di titun ni iro-inu nyin, ki nyin ki o le ri idi if lrun , ti o dara, ti o si e itwgb, ti o si p” (Romu 12:2). Bi a b f fi run e ile wa, tum si p a k w af ay yii. A o aapn pup lati w ara m ki a le j Iyawo Kristi. Ipenija: Nj o ti ri awn iis Onigbagb mtta gb? Nj o n pa ara r m lailabawn kuro ninu ay? 2